Nigerian gospel singer, Akadri Toyin musically known as Toyinlogo has blessed the world with a wonderful song titled, “Opelojasi”
Toyinlogo’s latest song “Opelojasi” is a wonderful masterpiece you’ll surely love to listen to every time you want to have a feel of good music.
Listen below:-
Toyinlogo - OPELOJASI Lyrics
Chorus:aa Opelojasi ee Opelojasi oba to somi
Mowalaye ojo oni tun sojumi
aa Opelojasi ee Opelojasi.
Verse1. Ojumitiri etimi ti gbo oro igbala
Enumitinso ise iyanure
Akaikatan nise re ninu ayemi
Iwo lo gbami nigba toju ogunle
Emiayino logo o titi ayemi o...
Chorus:aa Opelojasi ee Opelojasi oba to somi
Mowalaye ojo oni tun sojumi
aa Opelojasi ee Opelojasi.
Verse 2: ore re po layemi
Opo opo oo baba
Aanu re po lorimi
Opo opo oo baba
Alagbara ni o, o Oluwa
Obato fajulo han ota ayemi
Eni toda orun tikin togbeo
Iwo ni emi yo masin titi ayemi o.
Chorus:aa Opelojasi ee Opelojasi oba to somi
Mowalaye ojo oni tun sojumi
aa Opelojasi ee Opelojasi.
Gba opemi oba ara ose o baba
Gba opemi oba ogo mogbeoga o
Nigba timo joko o
Ti mo sesiro
Ibi totin bayemibo
Titi donio
Ore tose layemi o
Lati igba ewe mi wa
Mowaripe ese o
Oba awon oba.
Call. Ese o ese o ese o
ese
Respond: gba opemi oba ara ose o baba.
Call: gba ope o eledami baba ayeraye
Respond: gba opemi oba ara ose o baba.
Call: emi ti fi ayemi fun o tire ma lonse o
Respond: gba opemi oba ara ose o baba
Call: iwonikan nigbekele mi alagbawi eda
Respond: gba opemi oba ara ose o baba
Call: ese o ese o ese o ese
Respond: gba opemi oba ara ose o baba
0 Comments